Hold something
Bọbọ alaṣakaṣa
Aiyayayaya
Bọbọ alaṣakaṣa
O sọnu lapa b
O sọnu lapa c
Observation no be felony
Ma ṣogun s'ọ'gá ẹ, fowó ẹ jẹ Indomie
N gbọ, them say street no get memory?
O ga o, a fẹẹ to ten story
Everybody know it's a vibe
Gbajúgbajà ìlú mọ ka yìí
Ó ń gbé wọn lọ free ride
Ó ń sọnu this side
Bọbọ kan ń pede ọmọ mi pro
Ẹ ma wo ijo lẹsẹ negro
Tó n' gbọ vibe, kò ṣe ní jó
Ti àwọn Arabo gan ò ṣe kó
O ya, wọ'n ti sọ d'anthem
O wa dorin àwọn mandem
Ayé ò le, ọmọ Ọba n kí ẹ
Ìwọ ló lowo inu bank ẹ
Hold something
O sọnu lapa 'bi
Ka rí nnkan jẹ, ka rí nnkan chop
I'm displaying my own caricature
In a comical way
Ẹ jẹ kọmọ yín kawe
Mo wọ club, Italo mo gbé
Eyi ara, ara kenge
Make my body no calm
Ọmọ tún ni 'yo fam
Ẹ ni ìgbàgbó, pọja ilẹ yii yàtọ
Ó kan mí n'pakọ
What you saying fam, I'm going fam
Ìgbà n bá jo, lónílù gbélù (Gbelu)
Iṣẹ ọwọ Mr. Peteru
Apa, lo n jẹ the boy is very good
Ṣa làtẹwọ bí ti Cheribum
Gbe sori lati Lungu de Oniru
Bí alfa tó mọ kewu jù
London Lagos
O ya, wọ'n ti sọ d'anthem (Anthem)
O wa dorin àwọn mandem (Mandem)
Ayé ò le, ọmọ Ọba n kí ẹ
Ìwọ lo o lowo inu bank ẹ
Hold something
O sọnu lapa bi
O jí, ó bẹba, àti àmàlà Peckham
Everybody know it's a vibe
Gbajúgbajà ìlú mọ ka yìí
Ó ń gbé wọn lọ free ride
Ó ń sọnu this side
Bọbọ Kan n pede ọmọ mi pro (Bọbọ alaṣaṣaka)
Ẹ ma wo ijo lẹsẹ negro (Mandem)
Tó n' gbọ vibe, kò ṣe ní jó (Haibo)
Ti awọn Arabo gan-an o ṣe ko (Aiyayaya)
Ẹ ni ìgbàgbó, pọja ilẹ yii yàtọ'
Ó kan mí n'pakọ
What you saying fam, I'm going fam