Elige una pista para reproducir
(Mur-Mur-Murderer)
Ijọ buruku lo n'ijọ tuntun
Baba, ṣo n gbọ ohun aiye n sọ?
Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nnkan
Kẹ to d'aye at'ọrun
And that why me I put You first
In everything I do
O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ
Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
N'gba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ ohun aye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ lọwọ n yẹnu
Ikọ o ni kọ bala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere
Ẹyin to laye ẹ gb'ohun mi ṣaṣẹ pa
Abiyamọ aye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o
Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o
K'aye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu
Ay, ti n ba lu n'ṣe ni ko ma dun
Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
N'gba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ ohun aye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ lọwọ n yẹnu
Ikọ o ni kọ bala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere (ay)