Elige una pista para reproducir
Oh, baba yẹ, dáhùn sọ̀rọ̀ mi
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi
One big transaction, tó ma change story mi
Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi
Oh, babá ye, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (ob-, obah)
Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (wah dem a say?)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pín'rẹ d'odọ̀ mi
Wọn ni Naija ṣi ma dùn, but you dey America
E go better la ti n gbó la t'aye Abacha
Owo t'ọmọde bá kọ́ rí, á fi jẹ akara
If I see first money, mo ma sá lọ Canada
Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (shoday, kí lo dé?)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (hmm)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè)
Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pínrẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè)
Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (ibè ló má gbé)
Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (gbogbo ẹ ló ma gbé)
Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister
Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye
Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣi, kò ní s'ofo
They're trolling their father, I’m stoning pẹ̀lú kpoli, pẹ̀lú coco
Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo
Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ́ (dorime fún ọmọ ọpẹ́)
Ọmọ oro mi wá pẹ (ọmọ oro mi wá pẹ)
Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pín're, jọ̀wọ́ pín're d'odo mi
Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (dáhùn, dáhùn, dáhùn; dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, to ma change story mi (ehn)
Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi