Elige una pista para reproducir
Jk
Mo ti f'oro mi le o lowo o
Messiah o
Mo ti gbeke mi le o Messiah o
Mo ni o niwaju mo ni o leyin
Messiah o
Iwo nikan ni mo ni
Messiah o
Olorun apata mi mo gbeke le o o
Ibi Isadi giga abo mi
Messiah o
Olugbala Oluwosan mi
Messiah o
Mo ni o n o ni beru Ohun gbogbo
Messiah o
Saanu fun mi o Messiah o
Ran mi lowo Messiah o
Eru yi wuwo n o le daa gbe Oluwa
Iwo Alagbara laiye at'orun
Eni ba gbeke le o o ti Segun Messiah o
Awon Angeli won Jo won yo
Nitori Messiah o
Ki ni n o se ti n o ni gboruko re ga
Messiah o
Awamaridi Loro re o
Messiah o
Gbogbo Ilekun e maa wariri o
Niwaju messiah o
Eyin ile kekeke o egbonranu alagbara de
Eyin Oke giga giga e sa Wonu okun lo
Jesu Kristi ni Messiah o
O ti de gbogbo ogun ti se
Messiah Messiah messiah o Messiah o
Kilon je iberu niwaju iberu
Ma Ma je kaiye ri mi mu o
Messiah Messiah o
Ma Ma je ki ipe yi d'epe mo mi lowo
Messiah o
So mi lo so mi bo
Kin le f'ogo fun o o
Messiah Messiah o o
Iwo ni mo ni
Messiah Messiah o