Elige una pista para reproducir
Ọmọ, we get many verse
I like this (uh, uh)
Ta lo mọ'bi to tun ti gbọ?
Mo sọ pe mo tun ti ṣe
Lọla Oluwa, mo ti tun ṣere
Uh (I am Izzies production)
Yeah, o fẹ m'orukọ mi?
Segun mo n jẹ
Wọn ma n pe mi ni Lord of Ajasa
Lord of Flavor
Lord hush
Jẹ o mọ
Uh, check it out
Ọjọ re bi ana
Mo gbe bed mi sori, mo gba Bariga lọ
Akure lati n bọ
Accident pọ lọna, Oluwa lo ko mi yọ
A ma debẹ dandan, baba determination
Mo ti ji, mo ti jọgọ
Ọmọ, o pọ, a dẹ fọ fẹni kankan
'Cause a mọra wa gan-an, baba baddest recovery
Totally new something
9ice, ṣo ranti
Rice iya Ngozi?
Orin ta fi n kọ nigba yẹn
Wọn ṣi n jo si
Eko ile, ilu aje
Gbogbo ibi la wa ṣaye de
One bag pere ni mo gbe wọle
A fi ra motor, a di alaye
Dream come true, awa lo n jẹ bẹẹ
Mo sọ pe mi o sọ fun ẹ tẹlẹ
Nigba ti a n fọwọ lu table labẹtẹ
Tawọn ọmọ oṣi maa n fi wa ṣe yeye
Bad vibe, kia ni mo move away
Make them no dey use their negative energy spoil my day
Mi o kuku fọ, oju wọn lo ṣe
Iṣẹ ta ṣe silẹ wọn ṣi n kowo le
Jẹ k'ọn mọ, jẹ k'ọn mọ, jẹ k'ọn mọ
Ladies and gentlemen
This Lord of Ajasa (uh)
Ancestor, appreciate you for this
(It's Bizzle on the mix)