Ask about me, ask about me
Wọ'n ti lé mi, but wọ'n ò mú mi
Ọmọ Ọlọrun kò lè ṣù mí
Sekeseke bula
I'm still getting my mulla
Dollar pẹ'lú naira
Iku tó pa iya teacher
Ò le pa àwọn nigga
Kí ló ń fo lókè o (fo lókè)
Eye ló ń fo lókè o (fo lókè)
Kí ló ń rìn nílé (rìn nílé)
Àwọn ẹ'yàn ló máa ń rìn nílé
Matemi molẹ oh (ooh)
Matẹ oju ilé molẹ
Kómàbà dobale
Ìwọ ló máa fẹ"kọ'lé
O ò lè kú lẹ'
One man soldier
Mẹ'tà mẹ'tà gbọ'sa
Awilo Logomba
Fún mi lówó mi biza
Kesekese kasa
Kasakasa Blanca
I open Bible chapter
I step on the Satan
Mo pè'sù danu
Mo kan l'ẹsẹ' kan
Ọtamurẹ'gẹ' jìgan oh why, ooh why
They don't know, they don't know
They don't know, they don't know
I don go (they donnnnn know)
They wan know, they wan know
They wan know, they wan know
Where I'm going (I don gooooo)
Kí ló fà frapapapa
Kí ló fà pattern yẹn
Wọn fẹ' ká mi mọ'n ibẹ'yẹn
Ọpọn ti sùn finally
Ọpọn ti sùn finally
A ò b'ẹnu méjì ṣeré mọ'n
Ask about me, ask about me
Wọ'n ti lé mi, but wọ'n ò mú mi
Ọmọ Ọlọrun kò lè ṣù mí
Sekeseke bula
I'm still getting my mulla
Dollar pẹ'lú naira
Iku tó pa iya teacher
Ò le pa àwọn nigga
Kí ló ń fo lókè o (fo lókè)
Eye ló ń fo lókè o (fo lókè)
Kí ló ń rìn nílé (rìn nílé)
Àwọn ẹ'yàn ló máa ń rìn nílé
Matemi molẹ oh (ooh)
Matẹ oju ilé molẹ
Kómàbà dobale
Ìwọ ló máa fẹ"kọ'lé
O ò lè kú lẹ'
One man soldier
Mẹ'tà mẹ'tà gbọ'sa
Awilo Logomba
Fún mi lówó mi biza
Kesekese kasa
Kasakasa Blanca
I open Bible chapter
I step on the Satan
Mo pè'sù danu
Mo kan l'ẹsẹ' kan
Ọtamurẹ'gẹ' jìgan oh why, ooh why