Оберіть трек для відтворення

Ana mi sọrọ, Ẹ ṣeun o
Oni mi sọrọ, ye o, Ẹ ṣeun o
Ọla mi a sọrọ, Ẹ ṣeun o
Ijinlẹ ninu ijinlẹ, ye o, Ẹ ṣeun o
(Yea-e-yea) ana mi sọrọ (ana mi sọrọ o)
Ẹ seun o (mo lẹ ṣeun o)
Oni mi sọrọ, Ẹ ṣeun o (mo lẹ ṣeun o)
Ọla mi a sọrọ (yea-yea), Ẹ ṣeun o (Ẹ ṣeun o)
Ijinlẹ ninu ijinlẹ, ye o, Ẹ ṣeun o
Le, le, le
Aye o kọ k'ọn mu mi bu o, wọn o kọ k'ọn ri mi pa
Eniyan ó kọ ki n ṣa'lejẹ, ori ọmọ ku lo kọmọ yọ (na, na, na)
Yesterday no better my today o
Marykay no change to àtike o
Ọmọ ẹlẹran mi o wa jẹgun
O da mi loju, ọla mi a gbe ra o (oni mi sọrọ o, Ẹ ṣeun o), ye, ye, ye
Mo le'ni mi sọrọ (oni mi sọrọ), ye o (Ẹ ṣeun o)
Mo l'ọla mi a dara (ọla mi sọrọ, Ẹ ṣeun o)
Ijinlẹ ninu ijinlẹ, o-o, Ẹ ṣeun o
Mo ni ana mi sọrọ o (ana mi sọrọ o), ana mi sọrọ o (Ẹ ṣeun o)
Mo lo s'ọrọ o, o s'ọrọ (oni mi sọrọ, ye o, ẹ ṣeun o)
Ọla mi a biza (ọla mi a sọrọ, ẹ ṣeun o) lo, lo, lo
Ijinlẹ ninu ijinlẹ (ijinlẹ, ẹ ṣeun o)
A lọla mi a biza, ọla mi a gbe ra
Ọla mi a dara, Ẹ ṣeun o (ye, ye, ye)
(Ọla mi a biza), eniyan l'ỌlỌrun mi (ọla mi a gbe ra)
(Ọla mi a dara) a dara, ye, ye, o (Ẹ ṣeun o)
Ọlọrun to d'ọla mi mu o (ọla mi a biza)
Ọla mi a biza, a gbe ra (ọla mi a dara, ẹ ṣeun o)
Ẹkun o ṣe jina si mi o (ọla mi a biza), l'orukọ Oluwa (ọla mi a gbe ra)
Jesus my life is in Your hands o (ọla mi a dara), Ẹ ṣeun o