Оберіть трек для відтворення
Hold something
Haibo
Aiyayayayaya
Bóbo Aláṣàkàṣà
Say
Mo gbe sórí, gbe sí ejika
Aiyayayayaya
Odikwa pay the price
Apede tí wọn fi sílẹbù ka
Òròbòdò gbé ìlù wá
Ó'ún tó ti pákà ti pákà
(Papa di popopo)
Àkùkọ' bàbá mi láyé láyé
(papapa di popopo)
Àgìdì ò ṣe nibi gbogbo
Jẹn sáré fi lamba konto
Jẹn sáré unleash the dragon
(wa unleash the drags)
Ẹṣà mọ pé sia pọ
Ìrònú ò papo
Kò sí ẹyàn bẹ, owó ò má ago
(oh my days)
Wey my people where them dey
Àríyá yàn yàn tí yá
Èré alẹ òní den de
My lamba na pick n' pay
Bóyá ke bend down select am
Wọ'n jẹ' per day
Mr. Selecta
I monetize my play
Mi sọ di ere muka ray
Action Omo kulodo
Mo ti wèrè bọ, kí má lè lé
Aiyayayayaya
Don't go there, don't de be
I'm topping the charts NO LABEL
Old or new in the game, don't gbé gè sí
E fit wound person
Mo gbe sórí, gbe sí ejika
Aiyayayayaya
Odikwa pay the price
Apede tí wọ n fi sílẹbù ka
Òròbòdò gbé ìlù wá
Ó'ún tó ti pákà ti pákà
(papa di popopo)
Àkùkọ' bàbá mi láyé láyé
(papapa di popopo)
Àgìdì ò ṣe nibi gbogbo
Jẹn sáré fi lamba konto
Jẹn sáré unleash the dragon
Wa unleash the drags
Ẹ ṣà mọ pé sia pọ
Ìrònú ò papo
Kò sí ẹyàn bẹ, owó ò má ago
Oh my days
Ó ún tó mú olórí má jẹ' orí ẹja
Ló mu Alejo má ṣe bí Ọba
Security tó sọ bullion van
Ojú lórí, kò lè rí one pound
Kò lè rí pound kan tó máa fi rí ọkan
Before you go on soun, you better consult
Consult creator ta sela'da
Bí ilẹ̀ yìí ò rogbo, lo fa ise l'Ẹgbá
Lo fa ise l'Ẹgbá
Tase leda
Ma ko ma fa seteba
Má ṣáré
Má kánjú, Má
Má dúró sà